Ba o ku Ise o tan

About the Song

Ba o ku Ise o tan is a song that encourages you that whatever the situation may be, there is light at the end of the tunnel and when you still have that breadth in you, there is hope for you. Never lose hope, never lose focus. Put your total trust in God. I am optimistic there is hope for you.

Lyrics

Verse 1:
Gbogbo enia e ma gbo, ba o ku ise o tan, e teti beleje o, ba o ku ise o tan
Gbogbo enia e ma gbo mi mo ni ba o ku ise o tan, e teti beleje o, ba o ku ise o tan
B’oju orun ba dudu, ti kurukuru b’oju orun mole, to dabi eni pe ko si funfun, ile ayo re fere mo na,
dakun ro’ju duro ma ma se kun ore so gbo, Oluwa mi o sun, ko t’ogbe o, yo da o lohun, o di dandan.

Verse 2:
O le ma la ‘soro kan koja, boya gbogbo re ti su o, o le je lori aya ni, o si le je lori oko, o ti e le je lori awon omo, gbogbo ise e le ti doju ru, s’owo sa fere fun o, o wowa, o wehin ko s’oluranlowo, mo nfi da o loju ore mi, pe ba o ku ise o tan.

Verse 3:
Ni igba kan ri, ohun gbogbo le fun mi koko ni, ati je ati mu se o, o le koko bi oju eja, mo gbadura mo gbawe titi, o dabi p’Olorun jina si mi, aimoye iso oru, adura fe e le d’ogede mo mi lenu, a s’Olorun mi nbe loke o, a s’eyiowu Eledumare Oba. L’ojo t’ori ma ba mi se, lo gbe mi pade olore, mi o ti e lagun jina rara ti mo fi wo’nu ire ayo mi lo. Divine connection lo je fun mi l’ojo aye mi, emi ti mo ti nf’abo mafo jeun, mo wa njeun ninu awon tanganran. Boya ti e jo t’emi, iwo ore mi ma ma ronu mo, eleti gbohun gbaroye o yo gbe o soke, yo da o lare. Sugbon wait for your time, aimasiko lo ndamu eda l’aye, bi gbogbo wa ba m’ojo atila, a o kuku ma sun, a o kawo gbera.

Call: Ma ma ro’ra re pin, ba o ku ise o tan (Ma a ro pin, ba o ku ise o tan)
Call: Mo ni o ma ro’ra re pin ba o ku ise o tan mo wi o / Kini ‘soro to ni laye tera mo adura Baba a gbo o / S’aye ti so fun o p’o pari, ona abayo wa repete fun o / Se won ti so p’o le l’omo l’aye, ma ronu mo omo nbo wa / S’owo lo nwa l’aye re, so fun Jehovah Jireh Oba, ma lo seso / S’o ro p’aye ti b’ojo ola re je, your future is bright mo so fun o / Oba t’o se ti Jabesi, o wa laye a se ti e fun e / Oun lo so Modekai deni nla dajudaju ko le gbagbe re / O mu talaka lat’ori akitan wa, o mu won joko pel’awon ‘mo Alade / Apoti eri wo ‘le Obedi-Edomu, o deni nla, o d’oloro repete / No condition is permanent isoro re fun ‘gba die ni mo wi / Pelu igbagbo ninu Olorun gbogbo ‘di Jeriko aye re a wo / Torina ma tori eyi ma be kiri, k’won ma ba fi o se jeunjeun so o gbo / Wara o si loni wara nbo bo d’ola ma para re ki wara ola ko to de / Ma ro pin ojo ola re dara.

Other Songs

E-Mail Addresses
  • omotaradivine@yahoo.com
  • omotaradivine@gmail.com
Phone Numbers
  • +2348050516103
  • +2348182932509
Social Handles